d:d:d:r:m
d::m:f:s:s:d:t:l:s:f:m:r:d:r:r:d:-
s:d:t:d:l:s:-m:s:-
s:d:t:d:l:s:m:r:
d:m:-f:s:s:d:t:l:-
s:f:m:m:r:d:r:r:d:
s:d:t:d:l:s::-m
1. Ibadan Ilu ori Oke
Ilu Ibukun Oluwa
K’oluwa se o nibukun
Fun onile at’alejo
Egbe: E ho e yo k’e sig be ‘rin
Ogo f’olorun wa l’orun
Ibukun ti Obangiji
Wa pelu re wo Ibadan
2. Ibadan ilu to ngbajeji
Ti ko si gbagbe omo re
K’ife arak ole wa nibe
Fun onile at’alejo
Egbe: E ho e yo K’e si gbe’rin etc:
3. Ibadan ilu jagunjagun
Awon toso d’ilu nla
Awa omo re ko ni je
K’ola ati ogo won run
Egbe: E ho e yo K’e si gbe’rin etc:
4. Mo wo lati ori oke
Bi ewa re ti dara to
B’odo re ko tile tobi
Sibe o la Ibadan ja
Egbe: E ho e yo k’e si gbe’rin etc:
5. Ibadan Ilu ori oke
K’oluwa se o ni bukun
Ki gbogbo ‘joye inu re
Je elemi gigun fun, wa
Egbe: E ho e yo k’e si ‘rin etc: